A máa tá tán ni pẹ̀lú Tani Olorun, nínú kó lọ sẹ́wọ̀n tí ọwọ́ òfin bá tẹ̀ ẹ́, tàbí ká fìdí rẹ̀mi - Agbejọ́rò Imam
Ninu fọnran ti Tani Olohun gbe soju opo ayelujara ti Facebook rẹ, o sọ pe agbẹjọro to n fi ẹwọn dunkooko mọ oun, ko mọ nnkan to n sọ, nitori pe ẹjọ ti ko...