Ajínigbé ń bèèrè N50m fún ìtúsílẹ̀ àwọn ọmọ tí wọ́n jí gbé -Òbi àwọn ọmọ ìlú Igboho ti wọ́n gbé lọ nípìńlẹ̀ Niger

Awọn ti wọn ji gbe naa n bọ lati ipinlẹ Sokoto, wọn ko si ajinigbe lọwọ lagbegbe Pelegi, Mokwa, nipinle Niger.

Read full coverage on TraceNews