Bukky Wright sọ̀rọ̀ lórí ikú Kola Oyewo àti Ogogo, bí wọn kò ṣe pe ọ̀pọ̀ àgbà òṣèré tó jìyà tíátà sí iṣẹ́ mọ́ àti ohun tí ìjọba le ṣe láti ṣèrànwọ́

Bukky Wright, lásìkò tó ń bá BBC News Yorùbá sọ̀rọ̀ nípa ikú àwọn òṣèré tíátà, ṣe àgbékalẹ̀ ọ̀nà bí ìjọba ṣe le ràn wọ́n lọ́wọ́ láti pọn omi sílẹ̀ de...

Read full coverage on TraceNews