Atẹjade ti kọmiṣanna feto iroyin ati ilanilọyẹ nipinlẹ naa, Idowu Ajanaku fi sita lọjọ Abamẹta to kọja fidi rẹ mulẹ pe igbesẹ naa waye lati dẹkun iku awọn...