Lara awọn ipinlẹ to ti buwọ lu ayajọ naa fawọn oniṣẹṣe naa la ti ri ipinlẹ Ogun, Eko ati Oyo, ti awọn ijọba naa si tun n kede olude fun gbogbo oṣiṣẹ...