Ọdún kan sẹ́yìn ni mo ti ń ṣàìsàn, dókítà kò sì mọ ohun tó ń ṣe mí - Opebe onítíátà

Ọjọ Iṣẹgun, ọsẹ yii ni Kunle Afod gbe fọnran ifọrọwerọ to ṣe pẹlu Ọpẹbẹ soju opo Youtube rẹ, to si n ṣe awọn eeyan ni kayeefi.

Read full coverage on TraceNews