Emmanuel Uduaghan, Gómìnà tẹ́lẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Delta jade láyé

Ninu atẹjade ti ọkan lara awọn mọlẹbi gomina tẹlẹ naa, Toju Anire Uduaghan fi sita lorukọ mọlẹbi, o sọ pe ibanujẹ ọkan lo jẹ fun awọn.

Read full coverage on TraceNews