"Èéfín ti gba gbogbo ara bàlúù náà lófurufú, Tí kìí bá ṣe pé awakọ̀ bàlúù náà dùú dáadáa ni, aráàlú ga ìbá kú nínú ìjàmbá náà"

Ninu alaye ti wọn ṣe fun BBC, wọn ni awọn ṣakiyesi bi baluu naa ṣe n fi sihin sọhun bi ẹni pe awakọ rẹ n jijadu ko maa balẹ si ibi ti ko yẹ.

Read full coverage on TraceNews