Igbimọ oluwadii naa ti adajọ Majisireeti Ayokunle Shiyanbola ko sodi ni wọn yoo ṣewadii ohun to ṣokunfa ikọlu naa, ṣe agbejade iye ati orukọ awọn to fori...