'Ibi alálàájì tó gẹṣin lọ Jumat lọmọ mi lọ tí wọ́n fi jíi gbé, bí mo ṣe ríi lẹ́yìn ọdún kan àti oṣù méjì rèé'

Ile iṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Oyo tun kede pe ọmọ metadinlogun lawọn doola nigba ti ọwọ tẹ afurasi meje lẹyin iṣẹ ìwádìí t'awọn ọlọpaa ṣe lori awọn gbọmọ-gbọmọ...

Read full coverage on TraceNews