Irọ́ ni Portable n pa wí pé mo gé òun jẹ, ohun tó ṣẹlẹ̀ lásìkò ìjà wa rèé - Charlse Okocha

Gbajumọ ori ayelujara naa, Charles Okocha jẹ ko di mimọ pe kii ṣe pe awọn kan deedee ṣagbekalẹ ija ti awọn ja laipẹ yii.

Read full coverage on TraceNews