Ìjọba Eko fèsì sí ẹ̀sùn tí obìnrin kan fi kan ilé ìwòsàn Randle nínú fídíò tó gba orí ayélujára
Ninu fidio naa ni obinrin kan ti fẹsun kan pe wọn pe oun ni owurọ ọjọ naa pe o rẹ ọmọ oun lati ibi iṣẹ ti oun si sare lọ pade wọn nile iwosan ijọba ti wọn...