Kọmiṣanaa fun eto Igbafẹ ati Aṣa nipinlẹ Oyo, Wasiu Olatunbosun, lo fidi eyi mulẹ fawọn akọroyin nibi ayẹyẹ naa to waye ni papa iṣere Adamasingba, niluu...