Jàǹdùkú kọlu áwọn olólùfẹ́ Oriyomi Hamzat, wọn ṣá wọn ní àdá, gún ìgò, sọ wọn ní òkúta, èèyàn kan kú, ọ̀pọ̀ tó farapa dèrò ilé ìwòsàn

Owurọ ọjọru ana ni isẹlẹ naa waye ni adugbo Molete nibi ti awọn ọmọ ẹgbẹ oselu Accord to lọwọọwọ si lati fi tijo tilu pade Oriyomi Hamzat to tilẹ UK de.

Read full coverage on TraceNews