Ìjàmbá ọkọ̀ ló sọ mí di ẹlẹ́sẹ̀ kan, ìdí eré ìdárayá Onídà ni mo ti ń gbọ́ bùkátà ọmọ méjì - Aanu Kumuyi
BBC News Yorùbá bá obìnrin àkàndá ẹ̀dá kan, tó ń kópa nínú eré ìdárayá Onídà, tí à mọ̀ sí Fencing sọ̀rọ̀ láti mọ̀ nípa eré ìdárayà náà àti ìpèníjà rẹ̀.