Kí ló dé tí ẹnu ń kun Sarafadeen Alli, olùdíje sípò gómìnà l'Oyo, torí fọ́nrán ibi tó ti gbé akẹ́kọ̀ọ́-kùnrin kan sórí ẹsẹ̀?

Ninu fọnran naa to n kaakiri ori ayelujara lati Ọjọru, ọsẹ yii, la ti ri Alli, ẹni to tun jẹ Sẹnetọ to n ṣoju ẹkun Guusu ipinlẹ Oyo lọwọ nile igbimọ...

Read full coverage on TraceNews