Kí ló fa rògbòdìyàn láàrín Bísọ̀ọ̀bù Onaiyekan àti ìjọba apapọ, tí wọn ṣe ń sọ̀kò ọ̀rọ̀ síra wọn?
Nibi ipade ọhun la gbọ pe awọn alakoso ijọ Katoliiki naa ti gbena woju Aarẹ Tinubu, leyi to jẹ ki ileeṣẹ aarẹ fibinu sọrọ si wọn lopin ọsẹ to kọja yii, ti...