Ọkọ̀ ojú omi tó kó èrò 77 yí dànù, èrò 46, tí ọ̀pọ̀ wọn jẹ́ ọmọdé kú, 15 yè, wọn ń wá àwọn èèyàn 16 tó kù

Atẹjade kan ti ileesẹ ọlọpaa nipinlẹ Sokoto fisita salaye pe eeyan mẹtadinlọgọrin lo wa ninu ọkọ oju omi naa.

Read full coverage on TraceNews