Gẹgẹbi ohun ti a gbọ, awọn ọmọ ẹgbẹ awakọ ero to wa labẹ igun kan naa ni wọn n ba ara wọn ja lori wi pe igun kan lo kan lati ṣe akoso ẹgbẹ naa.