Ero Arike rọ gbogbo ọmọ ẹgbẹ APC lati fọwọ wọnu ki wọn si ṣe ọkan akin tori bi ọrọ ibo ṣe maa n ri nigba mii niyẹn.