Kọmiṣanna ọlọpaa ipinlẹ Imo, Audu Garba Bosso, ti fidi ẹ mulẹ pe awọn ti mọ ibuba awọn ajinigbe naa ninu igbo, nibi ti wọn ko awọn ti wọn ji gbe naa si...