Wasila lo mura bi ọkunrin, to si lọ si oju ferese ibi ti eegun naa wa, lasiko ti wọn n mura fun n lọwọ lati wo o.