Ajọ INEC lo gbe awọn iwe ti Tinubu buwọ lu, to fi mọ awọn iwe ẹri rẹ soju opo wọn lọjọ Abamẹta to kọja yii, fun gbogbo eeyan lati ri.