Ọmọ ọdún 90 ni Ààrẹ Tinubu, Ó sì ń ṣàárẹ̀. ẹ̀rí tó dájú ń bẹ lọ́wọ́ mi - Atiku Abubakar, olùdíje ADC

Atiku ni ọjọ ori aarẹ ju eyi to n polongo fun gbogbo aye lọwọ yii ati wi pe ilera rẹ ko gbe iṣẹ akoso orilẹede Naijiria mọ.

Read full coverage on TraceNews