Ọmọ mẹ́fà kú s'ígbèkùn gbọ́mọ-gbọ́mọ tó ń ta àwọn ọmọdé l'Oyo, ọlọ́pàá dóòlà èèyàn 17, ọwọ́ tẹ afurasí alfa, babaláwo àtàwọn míì

Kọmíṣọ́nà ọlọ́pàá ipinlẹ Oyo, CP Abimbola Olugbenga lo fidi ọrọ yìí múlẹ fawọn akọroyin ni olú ileeṣẹ ọlọpaa to wa lagbegbe Eleyele niluu Ibadan lọjọ Aje...

Read full coverage on TraceNews