'Mi ò tíì fojú rí àwọn ọmọ mi fún ọdún mẹ́jọ, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ìtòsí ara la wà'

Ohun to n ba Ali lẹru bayii ni pe pẹlu bi ọrọ ṣe ri laarin igun mejeeji, afaimọ ko ma di eyi ti oun ko ni fi oju ri awọn ẹbi oun mọ layelaye.

Read full coverage on TraceNews