'Mo wá sí Naijiria láti kojú ọmọ Yahoo tó fẹ́ lu ìyá mi ni jìbìtì àmọ́ ohun tí mo bábọ̀ rèé'
Nọmba idanimọ ori foonu rẹ ṣafihan pe Naijiria lo ti n fi awọn atẹjiṣẹ ranṣẹ sori foonu iya Carlos lodi si Syria to ni oun wa gẹgẹ ọmọ ogun ilẹ Amẹrika to...