Ọmogun Naijiria dóòlà èrò ọkọ̀ 33 lọ́wọ́ ajínigbé, bẹ́ sínú igbó láti fọ́wọ́ òfin máwọn jàndùkú agbébọn náà
Agbẹnusọ fun ileeṣẹ ologun, Ọgagun Aliyu Danja, ṣalaye ninu atẹjade kan to fi sita wi pe lọsan an ọjọ Abamẹta ọjọ kẹjọ oṣu Kẹjọ ọdun yii ni ikọ ọmogun...