Ní bíi ọdún kan tí ọlọ́pàá yìnbọn pa èèyàn mẹ́ta nibi ìsìnkú Olóòtú ìjọba Kenya tẹ́lẹ̀, ìwádìí BBC jáde nipa ìṣẹ̀lẹ̀ náà
BBC se agbeyẹwo awọn aworan ati fidio to to ẹẹdẹgbẹjọ lati mọ ibi tawọn eeyan ti ibọn pa naa duro si lọjọ Kẹrindinlogun osu kẹwaa ọdun 2025, ti a si tun...