Nǹkan kan tí mo mọ̀ ni pé bí orin tí mo bá kọ bá bùkún fún mi, yóò bùkún fún gbogbo èèyàn tó bá gbọ́ ọ - Bisi Manuel
O ṣalaye pe oun ni igbagbọ pe nigba ti yoo ba fi di ọdun diẹ si asiko yii, awọn orilẹede miran ti ko gbọ ede Yoruba yoo bẹrẹ si ni ni ifẹ si gbigbọ orin...