Obìnrin tó bá rí Olóòlù, ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ yóò gbẹ lorí ìdúró ni, èyí tó bá ya fídíò rẹ̀ bíi Wasilat láì ṣe ìràpadà, yóò kú tàbí ya wèrè láàárín ọjọ́ keje - Ìdílé Olóòlù
Ishola sọ pe ka ni wọn ko ṣe gbogbo etutu irapada ti wọn ṣe fun Wasilat lọjọ naa ni, Ọjọru, ọsẹ yii ni obinrin naa ko ba jade laye, nitori pe ko sẹni to...