Atẹjade ti wọn fi soju opo X wọn lọjọ keje oṣu Kẹwaa ọdun 2026 yii ṣalaye pe, ṣadeede ni ọkunrin naa ko mọ ibi to wa mọ, ti ko si jọ pe o n mi mọ, ki ọkọ...