Olùṣọ́ Onadeko ọ̀rẹ́kùnrin Tope Osoba ṣàlàyé nǹkan tó mọ̀ nípa ikú gbajúmọ̀ òṣèré tó lọ àtàwọn ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn án

Wolii Onadeko ṣalaye ninu ifọrọwerọ ti o ṣe pẹlu Celestial Reality Check lopin ọsẹ to kọja wi pe ni agọ ọlọpaa ni Ikorodu nipinlẹ Eko ni Tope Osoba ku si.

Read full coverage on TraceNews