Nnkan bii aago mọkanla owurọ ọjọ Abamẹta,ọjọ kẹtadinlogun oṣu Kẹwaa ọdun 2026 yii ni olori awọn ṣọja naa balẹ si Maiduguri.