Owó ìrànwọ́ iná mọ̀nàmọ́ná tí ìjọba fẹ́ẹ́ yọ kúró ní 2027, ohun tí a mọ̀ rèé

Minisita to n ri si ọrọ ina mọnamọna ni Naijiria, Joseph Tegbe, ṣalaye pe igbesẹ yii ṣe pataki lati ri i pe ina ọba duro deede fun araalu lati ri lo.

Read full coverage on TraceNews