Pásítọ̀ tí wọ́n fẹ̀sùn kàn pé ó pàṣẹ káwọn òbí ìjọ rẹ̀ fi ebi pa ọmọ wọn kú yóò gba ìdájọ́ lónìí nílé ẹjọ́

Paul Mackenzie atawọn ọmọ ijọ rẹ mọkandinlọgbọn mii ni wọn fẹsun ipaniyan awọn ọmọde 191 kan.

Read full coverage on TraceNews