Èrò bàálù tó gbé àrùn Ebola wọ Kenya kú, wọ́n ń wá èèyàn 28 tó farakínra pẹ̀lú rẹ̀

Minisita feto ilera nilẹ Kenya, Aden Duale lo sisọ loju ọrọ naa pẹlu alaye pe ọmọ orilẹede naa kan, to ti n gbe ni orilẹede Congo tẹlẹ lati ọdun meje...

Read full coverage on TraceNews