Ọ̀rọ̀ oyè Awùjalẹ̀ tún gbọ̀nà míràn yọ; agboolé Fusengbuwa wọ́ ìjọba ìpínlẹ̀ Ogun àtàwọn Afọbajẹ lọ sílé ẹjọ́

Ileẹjọ giga to wa niluu Ijebu Ode ni wọn wọ ijọba ipinlẹ Ogun ati awọn Afọbajẹ lọ, nibi ti wọn ti n rọ ileẹjọ pe ko paṣẹ fun igbimọ Afọbajẹ lati bẹrẹ...

Read full coverage on TraceNews