Ọ̀rọ̀ oyè Awujale tún gba ọ̀nà míì yọ, bí igbákejì alága ìdílé Funsegbuwa ṣe wọ́ àwọn èèyàn tó ya kúrò nínú ìdílé lọ sílé ẹjọ́, bèèrè N10bn

Ni ọjọ Kẹrinlelogun, oṣu Kẹjọ ni Oloye Fassy wọ awọn eeyan naa lọ siwaju ile ẹjọ giga ipinlẹ Ogun fun ẹsun ibanilorukọjẹ to si n beere fun owo itanran...

Read full coverage on TraceNews