Ta ló ni agbárí èèyàn 28 àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ egungun èèyàn táwọn ọlọ́pàá rí nínú aginjù ní Abia?

Awọn to n ṣe iwadii iṣẹlẹ naa n sọ pe o ṣeeṣe ki awọn egungun agbari naa jẹ ti awọn eeyan ti wọn ji gbe lagbegbe naa.

Read full coverage on TraceNews