À ti tún àwọn ẹ̀rọ̀ BVAS wa ṣe láti dènà kí èèyàn kan lo káàdì ìdìbò ẹlòmíràn nínú ìdìbò gómìna l‘Osun - Alága INEC

BBC News Yorùbá bá alága àjọ elétò ìdìbò nílẹ̀ wa, Joash Amupitan sọ̀rọ̀ lásìkò àbẹ̀wò tó ṣe sí ìpínlẹ̀ Osun, ó sì ṣàlàyé ipò tí ìgbaradì INEC wà fétò...

Read full coverage on TraceNews