Tinubu gbọdọ̀ ṣàlàyé ìdí tó fi yan Yorùbá láti darí ẹ̀ka méjì gbóògì ní àjọ elétò ìdìbò INEC - Atiku
Atiku sọ ninu atẹjade náà wí pé ọmọ Naijiria nilo alaye lori iyansipo Arabinrin Oluyemi Titilayo Adeyemi-Showunmi ati Ọmọwe Lawrence Bayode gẹgẹ bíi adari...