Tinubu sọ̀rọ̀ fún ìgbà àkọ́kọ́ lórí ìtúsílẹ̀ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ Oriire lákàtà ajínigbé, kókó ohun tó sọ rèé
Aarẹ Bola Tinubu ni awọn ajinigbe naa beere owo ati itusilẹ awọn ikọ wọn to wa ni ọgba ẹwọn ki wọn too le tu awọn olukọ ati akẹkọọ to wa nigbekun wọn...