Ìwà tí ọ̀pọ̀ ‘Marketer’ ń hù, kù díẹ̀ káà tó, àwọn òṣèré gbà pé wọ́n gbọdọ́ gbéra sílẹ̀ fún wọn láti dìde - Nike Peller
BBC News Yorùbá wá gbajúmọ̀ òṣèré, Nike Peller kàn, láti mọ ìdí tí kò fi kópa nínú sinimá mọ́, àlàyé nípa idán pípa àti irúfẹ́ èèyàn tí bàbá rẹ̀ ọlọ́wọ́...