Ìwádìí bẹ̀rẹ̀ lórí fídíò tó ṣàfihàn báwọn ọlọ́pàá kan ti ṣe ìkọlù sí ọ̀dọ́kùnrin tó ń ta góòlù l'Eko

Ọlọpaa sọ pe ẹkun E (Area E) ni awọn ọlọpaa naa ti n ṣiṣẹ, ti a si gbọ pe asiko ti ọkunrin oni goolu naa fẹẹ lọ gbe ọja goolu fun onibara rẹ ni wọn da a...

Read full coverage on TraceNews