"Àwọn ọlọ́pàá ló wá kìlọ̀ fún wa pé ká kúrò nílé nítorí bandiiti, oṣù karùn-ùn rèé tí a ti ń wọ àwọ̀sùn kiri"Pasitọ Omoleyin

Alagba Omoleyin tẹsiwaju pe ọjọ kẹta lẹyin tawọn kuro nile ni awọn bandiiti lọọ ṣọṣẹ niluu abinibi oun ti won si pa awon eeyan nibẹ.

Read full coverage on TraceNews