Àwọn 'ọlọ́pàá' tó fẹ́ wá fi tipá gbé mi gbá ìdí ìbọn gbá ìyàwó mi, wọ́n sì bá oyún inú rẹ̀ jẹ́ – Tani Olohun

Tani Olohun sọ eyi ninu ifọrọwerọ pẹlu akoroyin BBC News yoruba nilu Ibadan. O ni kikugiri ti awọn eeyan naa ti wọn pe ara wọn ni ọlọpaa ku giri si oun...

Read full coverage on TraceNews