BBC ṣayẹwo awọn ọgbọn alumọkọrọyi marun-un tawọn ikọ apani n lo bayii lati fi ṣe ikọlu apanirun, bí wọn ko ṣe fi ikọlu yii mọ lori araalu lasan mọ.