Wo orúkọ ọmọ Naijiria 24 tí àjọ DHS fọwọ́ òfin mú lórí onírúurú ẹ̀sùn ìwà ọ̀daràn lórílẹ́èdè Amẹrika
Lara awọn ẹsun ti wọn fi kan wọn ni fifi owo ranṣẹ soke okun lọna aitọ, ẹsun iwa ọdaran lori gbigbe egboogi oloro, iwe yiyi, lilo ohun ija oloro lọna ti...