Wo àwọn ohun tó ṣẹlẹ̀ nígbà táwọn àgbà òṣèré tíátá wọlé àdúrà fún Taiwo Hassan Ogogo lórí àìsàn Jẹjẹrẹ
Inu gbọngan Babajide Olushola Sanwo-Olu ti ileeṣẹ amohunmaworan tipinlẹ Eko, LTV 8 to wa lagbegbe Agidingbi ni eto adura ọhun ti waye, lati fi ifẹ han si...